Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 1:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Àwọn ènìyàn búburú fi àwọ̀n wọn gbé wọn ṣókèó sì kó wọn jọ nínú àwọ̀n-ńlá rẹ̀;nítorí náà, ó dunnú, ó sì yọ̀ pẹ̀lú.

16. Nítorí náà, ó rúbọ sí àwọ̀n rẹ̀,ó sì ń ṣun tùràrí fún àwọ̀n-ńlá rẹ̀nítorí pẹ̀lú àwọ̀n rẹ̀ ni ó fí ń gbé ní ìgbádùntí ó sì ń gbádùn pẹ̀lú oúnjẹ tí ó bá wù ú.

17. Ǹjẹ́ wọn yóò ha máa pá àwọ̀n wọn mọ́ ní òfìfo bí,tí wọn yóò sí pa orílẹ̀-èdè run láìsí àánú?

Ka pipe ipin Hábákúkù 1