Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ọlọ́lá ìgbéríko, àwọn alákòóso, àwọn baálẹ̀ àti àwọn onídàájọ́ ọba ran àwọn Júù lọ́wọ́, nítorí wọ́n bẹ̀rù u Módékáì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:3 ni o tọ