Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 9:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Nítorí náà a pe àwọn ọjọ́ wọ̀nyí ní Púrímù, láti ara ọ̀rọ̀ Púrì). Nítorí ohun gbogbo tí a kọ sínú ìwé yìí àti nítorí ohun tí wọ́n ti rí àti ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ sí wọn,

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:26 ni o tọ