Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lákókò yìí, àwọn tó kù nínú àwọn Júù tí wọ́n wà ní agbégbé ọba náà tún kó ara wọn jọ láti dáàbò bo ara wọn kí wọn sì sinmi lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá a wọn. Wọ́n sì pa ẹgbàá mẹ́tadínlógójì ó lé ẹgbẹ̀rin (75,000) àwọn tí ó kóòríra wọn ṣùgbọ́n wọn kò fi ọwọ́ọ wọn lé ìkógún un wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:16 ni o tọ