Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì sọ fún Ẹ́sítà ayaba pé, “Àwọn Júù ti pa ẹ̀ẹ́dẹ̀gbẹ̀ta (500) ọkùnrin àti àwọn ọmọkùnrin mẹ́wẹ̀ẹ̀wá tí i ṣe ọmọ Hámánì ní ilé ìṣọ́ Ṣúṣà run. Kí ni wọ́n ṣe ní gbogbo ìgbèríko ọba tó kù? Báyìí kí ni ẹ̀bẹ̀ rẹ? A ó fi fún ọ. Kí ni ìbéèrè rẹ? A ó sì tún fi fún ọ.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:12 ni o tọ