Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, oṣù Ádárì, tí ó yẹ kí a mú àṣẹ tí ọba pa wá sí ìmúṣẹ. Ní ọjọ́ yìí ni ọ̀tá àwọn Júù rò pé àwọn yóò borí i wọn, ṣùgbọ́n nísinsin yìí a ti yìí padà, àwọn Júù sì na ọwọ́ agbára tó ga lórí àwọn tí ó kóòríra wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:1 ni o tọ