Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ́sítà sì dáhùn pé, “Bí ó bá tẹ́ ọba lọ́rùn, jẹ́ kí ọba, pẹ̀lúu Hámánì, wá lónìí sí ibi àṣè tí èmi ti pèṣè fún-un.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:4 ni o tọ