Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n gbogbo èyí kò ì tíì tẹ́ mi lọ́rùn níwọ̀n ìgbà tí mo bá sì ń rí Módékáì aráa Júù yẹn tí ó ń jòkòó lẹ́nu ọ̀nà ọba.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:13 ni o tọ