Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ, kí o kó gbogbo àwọn Júù tí ó wà ní Ṣúsà jọ, kí ẹ sì gbààwẹ̀ fún mi. Ẹ má ṣe jẹun tàbí omi fún ọjọ́ mẹ́ta, ní òru àti ní ọ̀ṣán. Èmi àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin mi náà yóò gbààwẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin náà ti ṣe. Nígbà tí ẹ bá ṣe èyí, èmi yóò tọ ọba lọ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lòdì sí òfin. Bí mo bá sì ṣègbé, mo ṣègbé.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:16 ni o tọ