Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Hámánì sọ fún ọba Ṣérísésì pé, “Àwọn ènìyàn kan wà tí wọ́n fánká tí wọ́n sì túká ní ara àwọn ènìyàn ní gbogbo àgbáyé ìjọba rẹ̀ tí ìṣe wọn yàtọ̀ sí ti gbogbo àwọn tó kù tí wọn kò sì pa òfin ọba mọ́; èyí kì í ṣe ìfẹ́ ọba láti gbà fún wọn bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:8 ni o tọ