Nígbà náà ni àwọn ìjòyè ọba tí ó wà ní ẹnu ọ̀nà béèrè lọ́wọ́ Módékáì pé, “È éṣe tí ìwọ kò ṣe pa àṣẹ ọba mọ́.”