Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé kí ọba kí ó yan àwọn aláṣẹ ní gbogbo agbégbé ilẹ̀ ọba láti kó gbogbo àwọn arẹwà ọmọbìnrin wọ̀nyí jọ sí ilé àwọn obìnrin ní ilé ìṣọ́ Ṣúṣà. Kí a kó wọn fún ìtọ́jú Hégáì, ìwẹ̀fà ọba, ẹni tí ó ṣe olùtọ́jú àwọn obìnrin; kí a ṣe ìtọ́jú u wọn dáradára.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:3 ni o tọ