Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A mú Ésítà lọ síwájú ọba Ṣéríṣésì ní ibùgbé ọba ní oṣù kẹ́wàá, tí ó jẹ́ oṣù Tébétì, ní ọdún kéje ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:16 ni o tọ