Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní alẹ́ ni yóò lọ ṣíbẹ̀, tí ó bá sì di òwúrọ̀ yóò padà sí ilé kejì nínú ilé àwọn obìnrin ní abẹ́ ìtọ́jú Ṣáásígásì ìwẹ̀fà ọba ẹni tí ó máa ń ṣe ìtọ́jú àwọn àlè. Òun kò ní lọ sí ọ̀dọ̀ ọba mọ́ àyààfi tí inú ọba bá dùn síi, tí ó sì ránṣẹ́ pé ó ní orúkọ obìnrin.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:14 ni o tọ