Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, Ṣérísésì ọba sì dáwọ́ ìbínú un rẹ̀ dúró, ó rántí i Fásítì àti ohun tí ó ti ṣe àti àṣẹ tí ó pa nípa tirẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:1 ni o tọ