Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ yìí gan-an ni àwọn ọlọ́lá obinrin Páṣíà àti ti Médíánì tí wọ́n ti gbọ́ nípa ìwà ayaba wọn yóò ṣe bẹ́ẹ̀ sí gbogbo àwọn ìjòyè ọba bákan náà. Àfojúdi àti àìnírẹ́pọ̀ tí kò lópin yóò wà.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 1

Wo Ẹ́sítà 1:18 ni o tọ