Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó béèrè pé, “Kí ni a lè ṣe sí ayaba Fásítì gẹ́gẹ́ bí òfin? Nítorí kò tẹríba fún àṣẹ ọba Ṣérísésì tí àwọn ìwẹ̀fà ọba sọ fún un.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 1

Wo Ẹ́sítà 1:15 ni o tọ