Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 8:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Wọ̀nyí ni àwọ̀n olórí ìdílé àti àwọn tí ó fi orúkọ sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn tì wọn gòkè pẹ̀lú mi làti Bábílónì ní àkókò ìjọba Aritaṣéṣéṣì ọba:

2. Nínú àwọn ọmọ Fínéhásì, Gásómù;nínú àwọn ọmọ Ítamárì, Dáníẹ́lì;nínú àwọn ọmọ Dáfídì, Hátúsì,

3. nínú àwọn ọmọ Ṣekaníáyà;nínú àwọn ọmọ Párósì, Ṣekaríáyà, àti pé àádọ́jọ (150) ọkùnrin fi orùkọ sílẹ̀ pẹ̀lú rẹ;

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 8