Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò rẹ̀ láti Bábílónì ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kìn-ín-ní, ó sì dé Jérúsálẹ́mù ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù karùn-ún nítorí ọwọ́ àánú Ọlọ́run rẹ̀ wà ní ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:9 ni o tọ