Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ sì ní láti mọ̀ pé ìwọ kò ní àṣẹ láti sọ sisán owó orí, owó òde tàbí owó bodè di dandan fún àwọn àlùfáà, àwọn Léfì, àwọn akọrin, àwọn aṣọ́nà, àwọn òṣìṣẹ́ tẹ́ḿpìlì tàbí àwọn òṣìṣẹ́ mìíràn nínú ilé Ọlọ́run yìí.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:24 ni o tọ