Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 6:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohunkóhun tí wọ́n bá fẹ́—àwọn akọ ọ̀dọ́ màlúù, àwọn àgbò, ọ̀dọ́ àgùntàn fún ọrẹ sísun sí Ọlọ́run ọ̀run, àti jéró, iyọ̀, wáìnì àti òróró, ìfiyàn bí àwọn àlùfáà ní Jérúsálẹ́mù ti béèrè ni ẹ gbọdọ̀ fún wọn lójoojúmọ́ láì yẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:9 ni o tọ