Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì jẹ́ kí wúrà àti àwọn ohun èlò fàdákà ti ilé Ọlọ́run, tí Nebukadinésárì kó láti ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù tí ó sì kó lọ sí Bábílónì, di dídá padà sí àyè wọn nínú tẹ́ḿpìlì ní Jérúsálẹ́mù; kí a kó wọn sí inú ilé Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:5 ni o tọ