Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba fi èsì yìí ránṣẹ́ padà:Sí Réhúmì balógun, Ṣímíṣáì akọ̀wé àti àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn yóòkù tí ń gbé ní Samáríà àti ní òpópónà Yúfúrátè:Ìkíní.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4

Wo Ẹ́sírà 4:17 ni o tọ