Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù keje, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ní rú ọrẹ sísun sí Olúwa, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò ì tí ì fi ìpìlẹ̀ ilé Olúwa lélẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 3

Wo Ẹ́sírà 3:6 ni o tọ