Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wàyí o, wọ̀nyí ni àwọn ènìyàn agbègbè Júdà tí ó gòkè wá láti ìgbèkùn láàrin àwọn tí a kó lọ, ẹni tí Nebukadinésárì ọba Bábílónì ti fi agbára mú ní ìgbèkùn lọ sí Bábílónì (wọ́n padà sí Jérúsálẹ́mù àti Júdà. Olúkúlùkù sí ìlú rẹ̀,

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 2

Wo Ẹ́sírà 2:1 ni o tọ