23. Lára àwọn ọmọ Léfì:Jósábádì, Ṣíhíméì, Kéláéáyà (èyí tí í se Kélítà), Pétíáíyà, Júdà àti Élíásérì.
24. Nínú àwọn akọrin:Élíásíbù.Nínú àwọn asọ́nà:Sálúmù, Télémù àti Úrì.
25. Àti lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tókù:Nínú ìran Párósì:Rámíáyà, Ísíáyà, Málíkíjà, Míjámínì, Éléásánì, Málíkíjà àti Bénáíyà.
26. Nínú ìran Élámù:Mátaníáyà, Ṣékáríáyà, Jéhíélì, Ábídì, Jérémótì àti Élíjà.
27. Nínú àwọn ìran Ṣátítù:Élíóénáì, Élísíbù, Mátaníáyà, Jérémótì, Ṣábádì àti Ásísà.
28. Nínú àwọn ìran Bébáì:Jéhóánánì, Hánánáyà, Ṣábábáì àti Átaláì.
29. Nínú àwọn ìran Bánì:Mésúlámì, Málúkì, Ádáyà, Jásílíbù, Ṣéálì àti Jérémótì.
30. Nínú àwọn Páhátì Móábù:Ádínà, Kélálì, Bénáíáyà, Mááséíáyà, Mátítaníáyà, Bésálélì, Bínúì ati Mánásè.
31. Nínú àwọn ìran Hárímù:Élíásérì, Ísíjà, Málíkíjà àti Ṣémáíáyà, Ṣíméínì,
32. Bénjámínì, Málílúkì àti Ṣémáríà.
33. Nínú àwọn ìran Hásíúmù:Mátíténáì, Mátítatítayà, Ṣábádì, Élífélétì, Jérémáì, Mánásè àti Ṣíméhì.
34. Nínú àwọn ìran Bánì:Máádáì, Ámírámù, Úélì,
35. Bénáíáyà, Bédéíáyà, Kélúhì,
36. Fáníyà, Mérémótì, Élíásíbù,