Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn ènìyàn ti gbọ́ ìrora mi,ṣùgbọ́n kò sí olùtùnú fún mi.Àwọn ọ̀tá mi ti gbọ́ ìparun mi;wọ́n yọ̀ sí ohun tí o ṣe.Kí o mú ọjọ́ tí o ti kéde,kí wọ́n le dàbí tèmi.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:21 ni o tọ