Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìdí nìyí tí mo fi ń sunkúntí omijé sì ń dà lójú mi,Olùtùnú àti ẹni tí ó le mú ọkàn mi sọjí jìnnà sími,kò sí ẹni tí yóò dá ẹ̀mí mi padà.Àwọn ọmọ mi di aláìnínítorí ọ̀ta ti borí.”

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:16 ni o tọ