Báwo ni ìlú ṣe jókòó nìkan,nígbà kan tí ó sì kún fún ènìyàn!Ó ti fìgbà kan jẹ́ ìlú olókìkí láàrin àwọn orílẹ̀ èdè,tí ó wà nípò opó,Ẹni tí ó jẹ́ ọmọ ọba bìnrin láàrin ìlúni ó padà di ẹrú.