Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò rán àwọn ènìyàn rẹ̀ láti lọ ṣe ìwádìí, wọ́n sì rí pé ẹyọkan kò kú lára àwọn ẹran ọ̀sìn ará Ísírẹ́lì. Ṣíbẹ̀ náà, Fáráò kò yí ọkàn rẹ̀ padà àti pé kò jẹ́ kí àwọn ènìyàn ó lọ.

Ka pipe ipin Ékísódù 9

Wo Ékísódù 9:7 ni o tọ