Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ Olúwa yóò mú àrùn búburú wá sí ara ẹran ọ̀sìn nínú oko, sí ara ẹsin, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, rànkunmí, màlúù, àgùntàn àti ewúrẹ́ yín.

Ka pipe ipin Ékísódù 9

Wo Ékísódù 9:3 ni o tọ