Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 9:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè dá a lóhùn pé, “Bí mo bá ti jáde kúró ní àárin ilú, èmi yóò gbé ọwọ́ mi sókè sí Olúwa, sísàn àrá yóò dáwọ́ dúró, yìnyín kò sì ni rọ̀ mọ́, kí ìwọ kí ó lè mọ̀ pé Olúwa ni ó ni ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 9

Wo Ékísódù 9:29 ni o tọ