Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pàṣẹ nísin yìí láti kó ẹran-ọ̀sìn yin àti ohun gbogbo ti ẹ ni ní pápá wá sí abẹ́ ààbò, nítorí òjò yìnyín yóò rọ̀ sí orí àwọn ènìyàn àti ẹran ti a kò kó wá sí abẹ́ ààbò tí wọ́n sì wà ni orí pápá, wọn yóò sì kú.’ ”

Ka pipe ipin Ékísódù 9

Wo Ékísódù 9:19 ni o tọ