Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odò Náílì yóò kún fún ọ̀pọ̀lọpọ́ àwọn ọ̀pọ̀lọ́. Wọn yóò gókè wá sí ààfin rẹ, àti yàrá rẹ ni orí ìbùsùn rẹ. Wọn yóò gòkè wá sí ilé àwọn ìjòyè rẹ àti sí ara àwọn ènìyàn rẹ, àti sí ibi ìdáná rẹ, àti sí inú ìkòkò ìyẹ̀fun rẹ.

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:3 ni o tọ