Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 8:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè dáhùn ó wí pé, “Bí èmi bá ti kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ, èmi yóò gbàdúrà sí Olúwa, awọn esinsin yóò fi Fáráò, àwọn ìjòyè rẹ, àti àwọn ènìyàn rẹ sílẹ̀ ní ọ̀la ṣùgbọ́n ǹjẹ́ ìdánílójú wa pé Fáráò kò tún ni lo ẹ̀tàn láti má jẹ́ kí àwọn ènìyàn kí ó lọ rú ẹbọ sí Olúwa.”

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:29 ni o tọ