Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ kò bá jẹ́ kí àwọn ènìyàn mi kí ó lọ, èmi yóò rán ọ̀pọ̀lọpọ̀ eṣinṣin sí ara rẹ àti sí ara àwọn ìjòyè rẹ, àti sí ara àwọn ènìyàn rẹ̀, sí àwọn ilẹ̀ rẹ̀. Gbogbo ilé àwọn ará Éjíbítì ni yóò kún fún eṣinṣin àti orí ilẹ̀ tí wọ́n wà pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:21 ni o tọ