Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni gbogbo àwọn ará Éjíbítì bẹ̀rẹ̀ sí í gbẹ́ etí odò Náílì láti wá omi tí wọn yóò mu, nítorí wọn kò le è mu omi tí ó wà nínú odò náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:24 ni o tọ