Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni Olúwa wí: Nípa èyí ni ìwọ yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa. Wò ó, èmi yóò fi ọ̀pá ti ó wà ní ọwọ́ mi, èmi yóò ná omi tí ó wà nínú odò Náìlì yóò sì di ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:17 ni o tọ