Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ fún àwọn ará ilé Ísírẹ́lì: ‘Èmi ni Olúwa, Èmi yóò sọ yín di òmìnira kúró nínú àjàgà àwọn ará Éjíbítì. Èmi yóò sì gbà yín sílẹ̀ kúró ní oko ẹrú wọn. Èmi yóò dá a yín sílẹ̀ pẹ̀lú apá nínà (àwọn iṣẹ́ ìyanu) àti pẹ̀lú ìdájọ́ ńlá.

Ka pipe ipin Ékísódù 6

Wo Ékísódù 6:6 ni o tọ