Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámírámù sì fẹ́ Jókébédì arákùnrin baba rẹ̀ ní ìyàwó. Jókébédì sì bí Árónì àti Mósè fún un. Ámírámù lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé.

Ka pipe ipin Ékísódù 6

Wo Ékísódù 6:20 ni o tọ