Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni wọ́n wí pé, “Ọlọ́run àwọn Hébérù tí pàdé wa. Ní ìsinsìnyìí, jẹ́ kí a lọ ní ìrìn ọjọ́ mẹ́ta sínú ihà láti rú ẹbọ sí Olúwa Ọlọ́run wa, kí ó má ba á fi àjàkálẹ̀-àrùn tàbí idà bá wa jà.”

Ka pipe ipin Ékísódù 5

Wo Ékísódù 5:3 ni o tọ