Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 38:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Ó ṣe àrò fún pẹpẹ náà, àwọ̀n onídẹ, kí ó wà níṣàlẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ̀, dé ìdajì òkè pẹpẹ náà.

5. Ó dá òrùka idẹ láti mú kí ó di òpó igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin idẹ àrò náà mú.

6. Ó sì fi igi kasíà ṣe àwọn òpó náà, ó sì bò wọ́n pẹ̀lú idẹ.

7. Ó sì fi òpó náà bọ inú òrùka, nítorí kí ó lè wà ní ìhà pẹpẹ náà láti máa fi gbé e. Ó sì sé e ní oníhò nínú.

Ka pipe ipin Ékísódù 38