Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 38:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọgọ́run-ún talẹ́ntì fàdákà ní a lò láti fi dá ihò ìtẹ̀bọ̀ fún ibi mímọ́ àti fún aṣọ títa ọgọ́rùnún ihò ìtẹ̀bọ̀ nínú ọgọ́rùn-ún talẹ́ntì náà talẹ́ntì kan fún ihò ìtẹ̀bọ̀ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ékísódù 38

Wo Ékísódù 38:27 ni o tọ