Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 38:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ihò ìtẹ̀bọ̀ fún òpó náà idẹ ni. Ìkọ́ òpó náà àti ìgbànú tí ó wà lára òpó náà jẹ́ fàdákà, a sì bo orí wọn pẹ̀lú fàdákà; gbogbo àwọn òpó àgbàlá náà ní ìgbànú fàdákà.

Ka pipe ipin Ékísódù 38

Wo Ékísódù 38:17 ni o tọ