Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 37:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì se ọ̀pá fìtílà náà ní kìkì wúrà ó sì lù ú jáde, ọ̀pá rẹ̀, ìtànná ìfẹ́ rẹ̀, irudi rẹ àti ago rẹ̀, wọ́n jẹ́ òkan náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 37

Wo Ékísódù 37:17 ni o tọ