Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 34:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí pé, “Olúwa, bí èmi bá rí ojú rere rẹ, nígbà náà jẹ́ kí Olúwa lọ pẹ̀lú wa. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, ènìyàn ọlọ́rùn líle ni wọn, dárí búburú àti ẹ̀ṣẹ̀ wa jìn, kí o sì gbà wá gẹ́gẹ́ bí ìní rẹ.”

Ka pipe ipin Ékísódù 34

Wo Ékísódù 34:9 ni o tọ