Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 34:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àkọ́bí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ni kí ìwọ kí ó fi ọ̀dọ́ àgùntàn rà padà, ṣùgbọ́n bí ìwọ kò bá rà á padà, dá ọrùn rẹ̀. Ra gbogbo àkọ́bí ọkùnrin rẹ padà.“Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ wá ṣíwájú mi ní ọwọ́ òfo.

Ka pipe ipin Ékísódù 34

Wo Ékísódù 34:20 ni o tọ