Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 33:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè máa ń gbé àgọ́ náà, ó sì pa á sí ìta ibùdó, ó jìnnà díẹ̀ sí ibùdó, ó pè é ni “Àgọ́ àjọ.” Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń bèrè Olúwa yóò lọ sí ibi àgọ́ àjọ náà ní ìta ibùdó.

Ka pipe ipin Ékísódù 33

Wo Ékísódù 33:7 ni o tọ