Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 33:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí pé, “Èmi yóò sì mú gbogbo ire mí kọjá níwájú rẹ, Èmi yóò sì pòkìkí orúkọ Olúwa níwájú rẹ. Èmi yóò sàánú fún ẹni tí èmi yóò sàánú fún, èmi yóò sì ṣoore-ọ̀fẹ́ fún ẹni tí èmi yóò ṣoore-ọ̀fẹ́ fún.

Ka pipe ipin Ékísódù 33

Wo Ékísódù 33:19 ni o tọ