Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 31:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ìwọ kí ó sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ẹ̀yín gbọdọ̀ máa pa ọjọ́ ìsinmi mi mọ́. Èyí ni yóò jẹ́ àmì láàrin èmi àti ẹ̀yin fún ìrandíran tó ń bọ̀, nítorí kí ẹ̀yin lè mọ̀ pé èmi ni Olúwa, ẹni tí ó yà yín sí mímọ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 31

Wo Ékísódù 31:13 ni o tọ